10Johanani baba Asariah. (Òhun ni ó sìn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà nínú ilé Olúwa tí Solomoni kọ́ sí Jerusalẹmu).
11Asariah baba Amariah Amariah baba Ahitubu
12Ahitubu baba Sadoku. Sadoku baba Ṣallumu,
13Ṣallumu baba Hilkiah, Hilkiah baba Asariah,
14Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki.