1 Kronika 6

ọmọ Haṣabiah, ọmọ Amasiah, ọmọ Hilkiah,

1 Chronicles 6:45 (UKJV) The son of Hashabiah, the son of Amaziah, the son of Hilkiah,

43ọmọ Jahati, ọmọ Gerṣoni, ọmọ Lefi;

44láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Merari wà ní ọwọ́ òsì rẹ̀: Etani ọmọ Kiṣi, ọmọ Abdi, ọmọ Malluki,

45ọmọ Haṣabiah, ọmọ Amasiah, ọmọ Hilkiah,

46ọmọ Amisi, ọmọ Bani, ọmọ Ṣemeri,

47ọmọ Mahili, ọmọ Muṣi, ọmọ Merari, ọmọ Lefi.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.