1Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ní àkókò ìjọba ọba Artasasta ní Persia, Esra ọmọ Seraiah, ọmọ Asariah, ọmọ Hilkiah,
2ọmọ Ṣallumu, ọmọ Sadoku, ọmọ Ahitubu,
3ọmọ Amariah, ọmọ Asariah, ọmọ Meraioti,
4ọmọ Serahiah, ọmọ Ussi, ọmọ Bukki,
5ọmọ Abiṣua, ọmọ Finehasi, ọmọ Eleasari, ọmọ Aaroni olórí àlùfáà—