Gẹnẹsisi 15

àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu.

Genesis 15:20 (UKJV) And the Hittites, and the Perizzites, and the Rephaims,

18Ní ọjọ́ náà gan an ni Olúwa dá májẹ̀mú pẹ̀lú Abramu, ó sì wí pé, “Àwọn ìran rẹ ni èmi yóò fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Ejibiti dé odò ńlá Eufurate:

19ilẹ̀ àwọn ará Keni, àti ti ará Kenissiti, àti ará Kadmoni,

20àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu.

21Àti ti ará Amori, àti ti ará Kenaani, àti ti ará Girgaṣi àti ti ará Jebusi.”

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.