19Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati,
20Rabiti, Kiṣioni, Ebesi,
21Remeti, Eni-Gannimu, Eni-Hada àti Beti-Pasesi.
22Ààlà náà sì dé Tabori, Ṣahasuma, àti Beti-Ṣemeṣi, ó sì pin ní Jordani. Wọ́n sì jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún àti ìletò wọn.
23Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní ẹ̀yà Isakari, ní agbo ilé agbo ilé.