Ẹkún Jeremiah 3

Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

Lamentations 3:60 (UKJV) You have seen all their vengeance and all their imaginations against me.

58Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò, o ra ẹ̀mí mi padà.

59O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí mi. Gba ẹjọ́ mi ró!

60Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn, gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

61Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọn àti ìmọ̀ búburú wọn sí mi,

62ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọ sí mi ní gbogbo ọjọ́.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.