Nehemiah 7

Sattu jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (845)

Nehemiah 7:13 (UKJV) The children of Zattu, eight hundred forty and five.

11Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìnlá ó lé méjìdínlógún (2,818)

12Elamu jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀fà ó lé mẹ́rin (1,254)

13Sattu jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (845)

14Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760)

15Binnui jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́jọ (648)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.