38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930).
39Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)
40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)
41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
42Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).