Saamu 118

Jẹ́ kí ilé Aaroni wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé”.

Psalm 118:3 (UKJV) Let the house of Aaron now say, that his mercy endures for ever.

1Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó dára; àánú rẹ̀ dúró láéláé.

2Jẹ́ kí Israẹli wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé”.

3Jẹ́ kí ilé Aaroni wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé”.

4Jẹ́ kí àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa wí pé: “Àánú rẹ̀ dúró láéláé.”

5Nínú ìrora mi, mo sọkún sí Olúwa, ó sì dá mi lóhùn nípa pé ó tú mi sílẹ̀.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.