15àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini,
16àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati.
17Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki.
18Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.
19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.