17Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki.
18Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.
19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.
20Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.
21Hadoramu, Usali, Dikla,