1 Kronika 1

Hadoramu, Usali, Dikla,

1 Chronicles 1:21 (UKJV) Hadoram also, and Uzal, and Diklah,

19Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.

20Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.

21Hadoramu, Usali, Dikla,

22Ebali, Abimaeli, Ṣeba.

23Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.