37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.
38Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.
39Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.
40Àwọn ọmọ Ṣobali: Afiani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti Onamu. Àwọn ọmọ Sibeoni: Aiah àti Ana.
41Àwọn ọmọ Ana: Diṣoni. Àwọn ọmọ Diṣoni: Hemdani, Eṣbani, Itrani, àti Kerani.