1 Kronika 1

Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

1 Chronicles 1:37 (UKJV) The sons of Reuel; Nahath, Zerah, Shammah, and Mizzah.

35Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora.

36Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki.

37Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

38Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.

39Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.