43Àwọn ọmọ Hebroni: Kora, Tapua, Rekemu, àti Ṣema.
44Ṣema ni baba Rahamu, Rahamu sì jẹ́ baba fún Jorkeamu. Rekemu sì ni baba Ṣammai.
45Àwọn ọmọ Ṣammai ni Maoni, Maoni sì ni baba Beti-Suri.
46Efani obìnrin Kalebu sì ni ìyá Harani, Mosa àti Gasesi, Harani sì ni baba Gasesi.
47Àwọn ọmọ Jahdai: Regemu, Jotamu, Geṣani, Peleti, Efani àti Ṣaafu.