45Àwọn ọmọ Ṣammai ni Maoni, Maoni sì ni baba Beti-Suri.
46Efani obìnrin Kalebu sì ni ìyá Harani, Mosa àti Gasesi, Harani sì ni baba Gasesi.
47Àwọn ọmọ Jahdai: Regemu, Jotamu, Geṣani, Peleti, Efani àti Ṣaafu.
48Maaka obìnrin Kalebu sì ni ìyá Seberi àti Tirhana.
49Ó sì bí Ṣaafu baba Madmana, Ṣefa baba Makbena àti baba Gibeah, ọmọbìnrin Kalebu sì ni Aksa.