1 Kronika 6

Àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.

1 Chronicles 6:16 (UKJV) The sons of Levi; Gershom, Kohath, and Merari.

14Asariah baba Seraiah, pẹ̀lú Seraiah baba Josadaki.

15A kó Josadaki lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Juda àti Jerusalẹmu kúrò ní ìlú nípasẹ̀ Nebukadnessari.

16Àwọn ọmọ Lefi: Gerṣoni, Kohati àti Merari.

17Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

18Àwọn ọmọ Kohati: Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.