38ọmọ Isari, ọmọ Kohati, ọmọ Lefi, ọmọ Israẹli;
39Hemani sì darapọ̀ mọ́ Asafu, ẹni tí o sìn ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀: Asafu ọmọ Berekiah, ọmọ Ṣimea,
40ọmọ Mikaeli, ọmọ Baaseiah, ọmọ Malkiah
41ọmọ Etini, ọmọ Sera, ọmọ Adaiah,
42ọmọ Etani, ọmọ Simma, ọmọ Ṣimei,