Eksodu 36

Fún ìhà kejì, ìhà àríwá àgọ́ náà, wọ́n ṣe ogún pákó

Exodus 36:25 (UKJV) And for the other side of the tabernacle, which is toward the north corner, he made twenty boards,

23Ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà.

24Ó sì ṣe ogójì fàdákà ihò ìtẹ̀bọ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ wọn ìtẹ̀bọ̀ méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìsàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀.

25Fún ìhà kejì, ìhà àríwá àgọ́ náà, wọ́n ṣe ogún pákó

26àti ogójì ihò ìtẹ̀bọ̀ fàdákà méjì ní abẹ́ pákó kọ̀ọ̀kan.

27Ó ṣe pákó mẹ́fà sì ìkangun, ní ìkangun ìhà ìwọ̀-oòrùn àgọ́ náà,

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.