Esra 2

Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (642)

Ezra 2:10 (UKJV) The children of Bani, six hundred forty and two.

8Sattu jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rún ó lé márùn-ún (945)

9Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760)

10Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (642)

11Bebai jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mẹ́tàlélógún (623)

12Asgadi jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé méjìlélógún (1,222)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.