31Elamu mìíràn jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254)
32Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320).
33Lodi, Hadidi àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (725)
34Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345)
35Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630).