15Lára wọn ni Katati, Nahalali, Ṣimroni, Idala àti Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlá àti ìletò wọn.
16Ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn jẹ́ ìní Sebuluni, ní agbo ilé agbo ilé.
17Kèké kẹrin jáde fún Isakari, agbo ilé ní agbo ilé.
18Lára ilẹ̀ wọn ni èyí: Jesreeli, Kesuloti, Ṣunemu,
19Hafraimu, Ṣihoni, Anaharati,