44Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹ pé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ.
45Ó ti sọ wá di èérí àti ààtàn láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo.
46“Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọn gbòòrò sí wa.
47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.”
48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.