Ẹkún Jeremiah 3

Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi,

Lamentations 3:49 (UKJV) Mine eye trickes down, and ceases not, without any intermission.

47Àwa ti jìyà àti ìparun, nínú ìbẹ̀rù àti ewu.”

48Omijé ń sàn ní ojú mi bí odò nítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.

49Ojú mi kò dá fún omijé, láì sinmi,

50títí ìgbà tí Olúwa yóò síjú wolẹ̀ láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i.

51Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn mi nítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.