Marku 9

Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò.

Mark 9:49 (UKJV) For every one shall be salted with fire, and every sacrifice shall be salted with salt.

47Bí ojú rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì.

48Níbi ti “ ‘kòkòrò wọn kì í kú, tí iná kì í sì í kú.’

49Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò.

50“Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mú un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ní àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.