27ní Hasari-Ṣuali, ní Beerṣeba àti àwọn agbègbè rẹ̀.
28Ní Siklagi, ní Mekona àti àwọn ìletò rẹ̀,
29ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu,
30Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní Lakiṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Aseka àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Beerṣeba títí dé àfonífojì Hinnomu.
31Àwọn ọmọ Benjamini láti Geba ń gbé ní Mikmasi, Aija, Beteli àti àwọn ìletò rẹ̀.