19Bigfai jẹ́ ẹgbàá ó lé mẹ́tàdínláàádọ́rin (2,067)
20Adini jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀ta ó lé márùn-ún (655)
21Ateri (láti ipasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́rùn-ún (98)
22Haṣumu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó ó lé mẹ́jọ (328)
23Besai jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó ó lé mẹ́rin (324)