Nehemiah 7

Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320)

Nehemiah 7:35 (UKJV) The children of Harim, three hundred and twenty.

33Nebo mìíràn jẹ́ méjìléláàádọ́ta (52)

34Elamu mìíràn jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254)

35Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320)

36Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345).

37Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.