35Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320)
36Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345).
37Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721)
38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930).
39Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)