9Láti ọ̀dọ̀ Sebuluni, Eliabu ọmọ Heloni.
10Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Josẹfu: láti ọ̀dọ̀ Efraimu, Eliṣama ọmọ Ammihudu. Láti ọ̀dọ̀ Manase, Gamalieli ọmọ Pedasuri.
11Láti ọ̀dọ̀ Benjamini, Abidani ọmọ Gideoni.
12Láti ọ̀dọ̀ Dani, Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai.
13Láti ọ̀dọ̀ Aṣeri, Pagieli ọmọ Okanri.