Numeri 1

A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.

Numbers 1:47 (UKJV) But the Levites after the tribe of their fathers were not numbered among them.

45Gbogbo ọmọkùnrin Israẹli tó jẹ́ ọmọ ogún ọdún sókè, tó sì lè lọ sójú ogun ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.

46Àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé egbèjìdínlógún dín làádọ́ta (603,550).

47A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.

48Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé,

49“Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.