Numeri 32

pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn.

Numbers 32:36 (UKJV) And Bethnimrah, and Bethharan, fenced cities: and folds for sheep.

34Àwọn ará Gadi wọ́n kọ́ Diboni, Atarotu, Aroeri;

35pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha,

36pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn.

37Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu,

38pẹ̀lú Nebo pẹ̀lú Baali-Meoni (wọ́n pàrọ̀ orúkọ wọn) àti Sibma. Wọ́n sì sọ ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ mìíràn.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.