9Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama: Ṣeba àti Dedani.
10Kuṣi sì bí Nimrodu ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
11Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu,
12Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.
13Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, àti Heti,