3Ahieseri olórí wọn àti Joaṣi àwọn ọmọ Ṣemaah ará Gibeah: Jeṣieli àti Peleti ọmọ Asmafeti, Beraka, Jehu ará Anatoti.
4Àti Iṣmaiah ará Gibeoni, ọkùnrin alágbára kan lára àwọn ọgbọ̀n ẹni tí ó jẹ́ olórí nínú àwọn ọgbọ̀n; Jeremiah, Jahasieli, Johanani, Josabadi ará Gedera,
5Elusai, Jerimoti, Bealiah, Ṣemariah àti Ṣefatia ará Harufiti;
6Elkana, Iṣiah, Asareeli, Joeseri àti Jaṣobeamu ará Kora;
7àti Joẹla, àti Sebadiah àwọn ọmọ Jerohamu láti Gedori.