25Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi; nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah.
26Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi. Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno.
27Àwọn ọmọ Merari. Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri.
28Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ.
29Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli.