2Àwọn ọmọ Kohati: Amramu, Isari, Hebroni, àti Usieli.
3Àwọn ọmọ Amramu: Aaroni, Mose àti Miriamu. Àwọn ọmọkùnrin Aaroni: Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.
4Eleasari jẹ́ baba Finehasi, Finehasi baba Abiṣua
5Abiṣua baba Bukki, Bukki baba Ussi,
6Ussi baba Serahiah, Serahiah baba Meraioti,