6Ussi baba Serahiah, Serahiah baba Meraioti,
7Meraioti baba Amariah, Amariah baba Ahitubu
8Ahitubu baba Sadoku, Sadoku baba Ahimasi,
9Ahimasi baba Asariah, Asariah baba Johanani,
10Johanani baba Asariah. (Òhun ni ó sìn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà nínú ilé Olúwa tí Solomoni kọ́ sí Jerusalẹmu).