1 Kronika 9

Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.

1 Chronicles 9:39 (UKJV) And Ner brings forth Kish; and Kish brings forth Saul; and Saul brings forth Jonathan, and Malchishua, and Abinadab, and Eshbaal.

37Gedori, Ahio, Sekariah àti Mikiloti.

38Mikiloti jẹ́ baba Ṣimeamu, àwọn náà ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu.

39Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba a Saulu, àti Saulu baba a Jonatani, àti Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.

40Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika.

41Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.