40Maknadebai, Sasai, Ṣarai,
41Asareeli, Ṣelemiah, Ṣemariah,
42Ṣallumu, Amariah àti Josẹfu.
43Nínú àwọn ìran Nebo: Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Sebina, Jaddai, Joẹli àti Benaiah.
44Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipasẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.