Esra 2

Ateri (nípasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́run (98)

Ezra 2:16 (UKJV) The children of Ater of Hezekiah, ninety and eight.

14Bigfai jẹ́ ẹgbàá ó lé mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (2,056)

15Adini jẹ́ àádọ́ta lé ní irinwó ó lé mẹ́rin (454)

16Ateri (nípasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́run (98)

17Besai jẹ́ ọrùndínnírinwó ó lé mẹ́ta (323)

18Jora jẹ́ méjìléláàádọ́fà (112)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.