Esra 2

Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122)

Ezra 2:27 (UKJV) The men of Michmas, an hundred twenty and two.

25Kiriati-Jearimu, Kefira àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743)

26Rama àti Geba jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mọ́kànlélógún (621)

27Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122)

28Beteli àti Ai jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223)

29Nebo jẹ́ méjìléláàádọ́ta (52)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.