8ilẹ̀ òkè, ní ẹsẹ̀ òkè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn òkè aginjù, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aginjù àti nì gúúsù ilẹ̀ àwọn ará: Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti àwọn ará Jebusi).
9Ọba Jeriko, ọ̀kan ọba Ai (tí ó wà nítòsí Beteli), ọ̀kan
10ọba Jerusalẹmu, ọ̀kan ọba Hebroni, ọ̀kan
11ọba Jarmatu, ọ̀kan ọba Lakiṣi, ọ̀kan
12ọba Egloni, ọ̀kan ọba Geseri, ọ̀kan