Joṣua 15

Dannah, Kiriati-Sannnah (tí í ṣe Debiri),

Joshua 15:49 (UKJV) And Dannah, and Kirjathsannah, which is Debir,

47Aṣdodu, agbègbè ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gasa, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé odò Ejibiti àti agbègbè Òkun Ńlá.

48Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣamiri, Jattiri, Soko,

49Dannah, Kiriati-Sannnah (tí í ṣe Debiri),

50Anabu, Eṣitemo, Animu,

51Goṣeni, Holoni àti Giloni, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.