Ẹkún Jeremiah 3

Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀, bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́.

Lamentations 3:10 (UKJV) He was unto me as a bear lying in wait, and as a lion in secret places.

8Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́, ó kọ àdúrà mi.

9Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi; ó sì mú ọ̀nà mi wọ́.

10Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀, bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́.

11Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ ó fi mi sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́.

12Ó fa ọfà rẹ̀ yọ ó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.