Lefitiku 14

fún ara wíwú, fún èélá àti ibi ara tí ó ń dán yàtọ̀.

Leviticus 14:56 (UKJV) And for a rising, and for a scab, and for a bright spot:

54Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún èyíkéyìí ààrùn àwọ̀ ara tí ó le è ràn ká, fún làpálàpá,

55àti fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, àti ti ilé,

56fún ara wíwú, fún èélá àti ibi ara tí ó ń dán yàtọ̀.

57Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́. Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún ààrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.