Matiu 1

Elihudi ni baba Eleasari; Eleasari ni baba Mattani; Mattani ni baba Jakọbu;

Matthew 1:15 (UKJV) And Eliud brings forth Eleazar; and Eleazar brings forth Matthan; and Matthan brings forth Jacob;

13Serubbabeli ni baba Abihudi; Abihudi ni baba Eliakimu; Eliakimu ni baba Asori;

14Asori ni baba Sadoku; Sadoku ni baba Akimu; Akimu ni baba Elihudi;

15Elihudi ni baba Eleasari; Eleasari ni baba Mattani; Mattani ni baba Jakọbu;

16Jakọbu ni baba Josẹfu, ẹni tí ń ṣe ọkọ Maria, ìyá Jesu, ẹni tí í ṣe Kristi.

17Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo wọ́n jẹ́ ìran mẹ́rìnlá láti orí Abrahamu dé orí Dafidi, ìran mẹ́rìnlá á láti orí Dafidi títí dé ìkólọ sí Babeli, àti ìran mẹ́rìnlá láti ìkólọ títí dé orí Kristi.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.