Nehemiah 7

Kiriati-Jearimu, Kefira, àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743)

Nehemiah 7:29 (UKJV) The men of Kirjathjearim, Chephirah, and Beeroth, seven hundred forty and three.

27Anatoti jẹ́ méjìdínláàádóje (128)

28Beti-Asmafeti jẹ́ méjìlélógójì (42)

29Kiriati-Jearimu, Kefira, àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743)

30Rama àti Geba jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mọ́kànlélógún (621)

31Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.