Numeri 6

“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́.

Numbers 6:24 (UKJV) The LORD bless you, and keep you:

22Olúwa sọ fún Mose pé,

23“Sọ fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹ sọ fún wọn pé,

24“ ‘ “Kí Olúwa bùkún un yín, kí ó sì pa yín mọ́.

25Kí Olúwa kí o mú ojú rẹ̀ kí ó mọ́lẹ̀ sí i yín lára. Kí ó sì ṣàánú fún un yín.

26Kí Olúwa bojú wò yín, kí ó sì fún un yín ní àlàáfíà.” ’

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.