1 Kronika 7

Àwọn ọmọ Ṣomeri: Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu.

1 Chronicles 7:34 (UKJV) And the sons of Shamer; Ahi, and Rohgah, Jehubbah, and Aram.

32Heberi jẹ́ baba Jafileti, Ṣomeri àti Hotami àti ti arábìnrin wọn Ṣua.

33Àwọn ọmọ Jafileti: Pasaki, Bimhali àti Asifati. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jafileti.

34Àwọn ọmọ Ṣomeri: Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu.

35Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Helemu Sofahi, Imina, Ṣeleṣi àti Amali.

36Àwọn ọmọ Sofahi: Sua, Haniferi, Ṣuali, Beri, Imra.

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.