Esra 2

Gibbari jẹ́ márùndínlọ́gọ́rùn (95).

Ezra 2:20 (UKJV) The children of Gibbar, ninety and five.

18Jora jẹ́ méjìléláàádọ́fà (112)

19Haṣumu jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223)

20Gibbari jẹ́ márùndínlọ́gọ́rùn (95).

21Àwọn ọmọ Bẹtilẹhẹmu jẹ́ mẹ́tàlélọ́gọ́fà (123)

22Netofa jẹ́ mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (56)

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. Licensed CC BY-SA 4.0. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc.